15/02/2026
Psalms 100:1-5
[1]Ẹ ho iho ayọ̀ si Oluwa, ẹnyin ilẹ gbogbo.
(A Psalm of praise.) Make a joyful noise unto the LORD, all ye lands.
[2]Ẹ fi ayọ̀ sìn Oluwa: ẹ wá ti ẹnyin ti orin si iwaju rẹ̀.
Serve the LORD with gladness: come before his presence with singing.
[3]Ki ẹnyin ki o mọ̀ pe Oluwa, on li Ọlọrun: on li o dá wa, tirẹ̀ li awa; awa li enia rẹ̀, ati agutan papa rẹ̀.
Know ye that the LORD he is God: it is he that hath made us, and not we ourselves; we are his people, and the sheep of his pasture.
[4]Ẹ lọ si ẹnu ọ̀na rẹ̀ ti ẹnyin ti ọpẹ, ati si agbala rẹ̀ ti ẹnyin ti iyìn: ẹ ma dupẹ fun u, ki ẹ si ma fi ibukún fun orukọ rẹ̀.
Enter into his gates with thanksgiving, and into his courts with praise: be thankful unto him, and bless his name.
[5]Nitori ti Oluwa pọ̀ li ore; ãnu rẹ̀ kò nipẹkun; ati otitọ rẹ̀ lati iran-diran.
For the LORD is good; his mercy is everlasting; and his truth endureth to all generations.