Ojulowo itumo Ala Ati Ona Abayo

Ojulowo itumo Ala Ati Ona Abayo Fun Ekun rere alaye lori itumo ala ati ona Abayo lori è

02/07/2024
26/06/2024

ISE TI ENITIOBA SE ABURU SIWA TABI TIO DINA IRE AYE WA YIO FI KAN AGBAKO.

Ise yii kona wa ni owo kankan rara.... Asiri ni kiise oogun.. Asiri ni agba oogun... Ise yii koni ewu kankan rara, ejekia se kiakia.

ISENA RE:-
Ao fi iso (nail) tuntun lu oju agbon kan, ao wa ko omo eyo atare 42 si enu, ao je kunna daada, ao mu omi agbon le lori, ao wase adura wipe gbogbo eni toba ndimi lowo orire, ki oro re o dojuru patapata, ao fo agbon naa danu, ao ni je oo.. Tio bafe ki asiri yi sise fun oo daadaa koko share re si opolopo group, kio si fi comment re se adura fun mi kio to dawo le...

ENITI ISENA BAWU LATI SE SUGBON TIO FE KIA BA OHUN SE KIO MESSAGE MI LORI WHATSAPP (08102755099))

FUN IBEERE ABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI OGUN TI OUN DOJUKO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ((08102755099. ))

FOLLOW MI LATI JE AWON ORISIRISI ANFANI TOPO NIPA BI ASE NLO EWE ATI EGBO FUN IWOSAN ATI FUN ONA ABAYO..

@highlightASIRI ONA OLA everyoneAdewale Omo Ifayemi

Say a big Ameen
06/05/2024

Say a big Ameen

ÀWỌN DIE LARA ÀPẸRẸ TO ROMO ÒKÚ TO TÍ KÚ BÓYÁ OTI PÉ TÀBÍ KO TII PÉ PÚPÒ PART ONE 🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏(1)..Bi eniyan Bari ìyá è...
15/04/2024

ÀWỌN DIE LARA ÀPẸRẸ TO ROMO ÒKÚ TO TÍ KÚ BÓYÁ OTI PÉ TÀBÍ KO TII PÉ PÚPÒ PART ONE
🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏

(1)..

Bi eniyan Bari ìyá ènìyàn to ti kú tàbí Baba rẹ to ti kú to n sunkún loju àlá kiise àpẹẹrẹ rere inú rẹ kodun sì hi àwọn ọmọ tàbí ebi rẹ sen se leyin to kú tán

(2)

Bi eniyan Bari òkú tí aṣọ tí wọn fi sìn òkú yí doti púpò loju orun tabi ti aṣọ yí yamo òkú yí lára bíi akisa àwọn tí wọn nlo sì ibiti GRAVE ẹni náà wá kose amoju to rẹ daada wọn nda nkan egbin sori Grace è tàbí kí Grace ẹ ti wù kí oma rí ẹni tún ṣe

(3)
Bi abari ẹni tó ti kú tó ń parí wo ebi npami tàbí òùngbẹ ń gbẹ òun alayi kodara àwọn ọmọ tàbí ebi òkú yí kose saara fún òkú yí bose yẹ leyin re bí abati ṣe saara fún òkú yí tán inure yio dun daada siwa

(4)
Bi o bawari arare gegebi eniti oku sungbo awon eyan o sunkun emigigun ni
Ti awon eyan bawan sun ekun iku ojiji ni teramo Adura irapada emi ati opolopo awe
Eyi to jaju niki osun mo awon Agbalagba

(5)

Bi abari òkú to wá pẹ̀lú aṣọ funfun tó tún tó èso orisirisi sára loju orun alayi dara pupo inú idẹra lowa níwájú Olúwa rẹ pẹlu ìgbádùn

Ao matesiwaju ninu Apa keji 👉🏻👉🏻👉🏻

Ọlọ́run bawa ké gbogbo àwọn òkú orun wá pátá pátá kio bawa fi wọn sínú ọgbà idẹra rẹ Alijanna amin

Ojulowo itumo Ala Ati Ona AbayoWaladu Suruur Fans PageSheikh Olanrewaju HasbyrobbySheikh Nurulfaydho AlkaolaqyOJULOWO ITUMO ALA LILA
whatsApp 08064417560London DealsLamidi Hammed Unity NewAn'Nur Islamic foundationHighlights Myanmar 2Authentic Ogido Islamic TvRoksana vlogsFolake FlakkyfajJack Thor TV.9Studio I-witness ComedyJawe Wagbo Jamiu Toyin

Address

Agric Ishawo Ikorodu Lagos
Ibadan

Telephone

+18064417560

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ojulowo itumo Ala Ati Ona Abayo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share